ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 25:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 Ó máa gbé ikú mì* títí láé,+

      Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sì máa nu omijé kúrò ní ojú gbogbo èèyàn.+

      Ó máa mú ẹ̀gàn àwọn èèyàn rẹ̀ kúrò ní gbogbo ayé,

      Torí Jèhófà fúnra rẹ̀ ti sọ ọ́.

  • Àìsáyà 30:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Tí àwọn èèyàn bá ń gbé ní Síónì, ní Jerúsálẹ́mù,+ o ò ní sunkún rárá.+ Ó dájú pé ó máa ṣojúure sí ọ tí o bá kígbe fún ìrànlọ́wọ́; ó máa dá ọ lóhùn ní gbàrà tó bá gbọ́ ọ.+

  • Àìsáyà 35:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àwọn tí Jèhófà rà pa dà máa pa dà wá,+ wọ́n sì máa kígbe ayọ̀ wá sí Síónì.+

      Ayọ̀ tí kò lópin máa dé orí wọn ládé.+

      Wọ́n á máa yọ̀ gidigidi, inú wọn á sì máa dùn,

      Ẹ̀dùn ọkàn àti ìbànújẹ́ kò ní sí mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́