ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Hósíà 13:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Màá rà wọ́n pa dà lọ́wọ́ agbára Isà Òkú;*

      Màá gbà wọ́n pa dà lọ́wọ́ ikú.+

      Ìwọ Ikú, oró rẹ dà?+

      Ìwọ Isà Òkú, ìpanirun rẹ dà?+

      Síbẹ̀, mi ò ní fojú àánú wò wọ́n.*

  • 1 Kọ́ríńtì 15:54
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 54 Àmọ́ nígbà tí èyí tó lè bà jẹ́ bá gbé àìdíbàjẹ́ wọ̀, tí èyí tó lè kú sì gbé àìkú wọ̀, ìgbà náà ni ọ̀rọ̀ tó ti wà lákọsílẹ̀ máa ṣẹ pé: “A ti gbé ikú mì títí láé.”+

  • 2 Tímótì 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 àmọ́ nísinsìnyí ìfarahàn Olùgbàlà wa, Kristi Jésù,+ ti mú kó ṣe kedere, ẹni tó mú ikú kúrò,+ tó sì tipasẹ̀ ìhìn rere+ tan ìmọ́lẹ̀ sí ìyè+ àti àìdíbàjẹ́.+

  • Ìfihàn 20:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 A sì ju ikú àti Isà Òkú* sínú adágún iná.+ Èyí túmọ̀ sí ikú kejì,+ adágún iná náà.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́