Sáàmù 145:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Jèhófà ń gbé gbogbo àwọn tó ti fẹ́ ṣubú ró,+Ó sì ń gbé gbogbo àwọn tó dorí kodò dìde.+ 2 Kọ́ríńtì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Àmọ́ Ọlọ́run tó ń tu àwọn tí ìrẹ̀wẹ̀sì bá nínú,+ ti tù wá nínú bí Títù ṣe wà pẹ̀lú wa;