Sáàmù 146:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà ń la ojú àwọn afọ́jú;+Jèhófà ń gbé àwọn tó sorí kọ́ dìde;+Jèhófà nífẹ̀ẹ́ àwọn olódodo.