Diutarónómì 10:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba* àti opó,+ ó sì nífẹ̀ẹ́ àjèjì,+ ó ń fún un ní oúnjẹ àti aṣọ. Sáàmù 68:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Bàbá àwọn ọmọ aláìníbaba àti ẹni tó ń dáàbò bo* àwọn opó+Ni Ọlọ́run nínú ibùgbé rẹ̀ mímọ́.+
18 Ó ń ṣe ìdájọ́ òdodo fún ọmọ aláìníbaba* àti opó,+ ó sì nífẹ̀ẹ́ àjèjì,+ ó ń fún un ní oúnjẹ àti aṣọ.