Sáàmù 135:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ẹ yin Jáà, nítorí Jèhófà jẹ́ ẹni rere.+ Ẹ kọ orin ìyìn* sí orúkọ rẹ̀, nítorí ó dára.