Sáàmù 150:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 150 Ẹ yin Jáà!*+ Ẹ yin Ọlọ́run nínú ibi mímọ́ rẹ̀.+ Ẹ yìn ín nínú òfúrufú* agbára rẹ̀.+ Ìfihàn 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Jèhófà,* Ọlọ́run wa, ìwọ ló tọ́ sí láti gba ògo+ àti ọlá+ àti agbára,+ torí ìwọ lo dá ohun gbogbo,+ torí ìfẹ́ rẹ ni wọ́n ṣe wà, tí a sì dá wọn.”
11 “Jèhófà,* Ọlọ́run wa, ìwọ ló tọ́ sí láti gba ògo+ àti ọlá+ àti agbára,+ torí ìwọ lo dá ohun gbogbo,+ torí ìfẹ́ rẹ ni wọ́n ṣe wà, tí a sì dá wọn.”