Sáàmù 103:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀,+ tí ẹ jẹ́ alágbára ńlá,Tí ẹ̀ ń ṣe ohun tó sọ,+ tí ẹ sì ń fetí sí ohùn rẹ̀.* Lúùkù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Lójijì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ọmọ ogun ọ̀run+ wá bá áńgẹ́lì náà, wọ́n ń yin Ọlọ́run, wọ́n sì ń sọ pé:
20 Ẹ yin Jèhófà, gbogbo ẹ̀yin áńgẹ́lì rẹ̀,+ tí ẹ jẹ́ alágbára ńlá,Tí ẹ̀ ń ṣe ohun tó sọ,+ tí ẹ sì ń fetí sí ohùn rẹ̀.*