Sáàmù 100:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Kí ẹ mọ̀* pé Jèhófà ni Ọlọ́run.+ Òun ló dá wa, tirẹ̀ la sì jẹ́.*+ Àwa ni èèyàn rẹ̀ àti àgùntàn ibi ìjẹko rẹ̀.+ Àìsáyà 54:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+ Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+
3 Kí ẹ mọ̀* pé Jèhófà ni Ọlọ́run.+ Òun ló dá wa, tirẹ̀ la sì jẹ́.*+ Àwa ni èèyàn rẹ̀ àti àgùntàn ibi ìjẹko rẹ̀.+
5 “Torí pé Aṣẹ̀dá rẹ Atóbilọ́lá+ dà bí ọkọ* rẹ,+Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni orúkọ rẹ̀,Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì sì ni Olùtúnrà rẹ.+ Ọlọ́run gbogbo ayé la ó máa pè é.+