Sáàmù 132:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Màá gbé ìgbàlà wọ àwọn àlùfáà rẹ̀,+Àwọn adúróṣinṣin rẹ̀ yóò sì kígbe ayọ̀.+ Àìsáyà 61:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Màá yọ̀ gidigidi nínú Jèhófà. Gbogbo ara mi* máa yọ̀ nínú Ọlọ́run mi.+ Torí ó ti fi ẹ̀wù ìgbàlà wọ̀ mí;+Ó ti fi aṣọ òdodo* bò mí lára,Bí ọkọ ìyàwó tó wé láwàní bíi ti àlùfáà+Àti bí ìyàwó tó fi àwọn ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀ ṣe ara rẹ̀ lọ́ṣọ̀ọ́.
10 Màá yọ̀ gidigidi nínú Jèhófà. Gbogbo ara mi* máa yọ̀ nínú Ọlọ́run mi.+ Torí ó ti fi ẹ̀wù ìgbàlà wọ̀ mí;+Ó ti fi aṣọ òdodo* bò mí lára,Bí ọkọ ìyàwó tó wé láwàní bíi ti àlùfáà+Àti bí ìyàwó tó fi àwọn ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀ ṣe ara rẹ̀ lọ́ṣọ̀ọ́.