Sáàmù 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí olódodo ni Jèhófà;+ ó nífẹ̀ẹ́ àwọn iṣẹ́ òdodo.+ Àwọn adúróṣinṣin yóò rí ojú* rẹ̀.+