Sáàmù 16:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mo gbé Jèhófà síwájú mi nígbà gbogbo.+ Torí pé ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún mi, mìmì kan ò ní mì mí.*+