-
Mátíù 27:41-43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
41 Bákan náà, àwọn olórí àlùfáà àti àwọn akọ̀wé òfin pẹ̀lú àwọn àgbààgbà bẹ̀rẹ̀ sí í fi ṣe yẹ̀yẹ́, wọ́n ń sọ pé:+ 42 “Ó gba àwọn ẹlòmíì là; kò lè gba ara rẹ̀ là! Òun ni Ọba Ísírẹ́lì;+ kó sọ̀ kalẹ̀ báyìí látorí òpó igi oró,* a sì máa gbà á gbọ́. 43 Ó ti gbẹ́kẹ̀ lé Ọlọ́run; kí Ó gbà á sílẹ̀ báyìí tí Ó bá fẹ́ ẹ,+ torí ó sọ pé, ‘Ọmọ Ọlọ́run ni mí.’”+
-