Sáàmù 57:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn kìnnìún yí mi* ká;+Àárín àwọn tó fẹ́ fà mí ya ni mo dùbúlẹ̀ sí,Àwọn tí eyín wọn jẹ́ ọ̀kọ̀ àti ọfà,Tí ahọ́n wọn sì jẹ́ idà mímú.+ 1 Pétérù 5:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ máa ronú bó ṣe tọ́, ẹ wà lójúfò!+ Èṣù tó jẹ́ ọ̀tá yín ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, ó ń wá bó ṣe máa pani jẹ.*+
4 Àwọn kìnnìún yí mi* ká;+Àárín àwọn tó fẹ́ fà mí ya ni mo dùbúlẹ̀ sí,Àwọn tí eyín wọn jẹ́ ọ̀kọ̀ àti ọfà,Tí ahọ́n wọn sì jẹ́ idà mímú.+
8 Ẹ máa ronú bó ṣe tọ́, ẹ wà lójúfò!+ Èṣù tó jẹ́ ọ̀tá yín ń rìn káàkiri bíi kìnnìún tó ń ké ramúramù, ó ń wá bó ṣe máa pani jẹ.*+