Sáàmù 35:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Jèhófà, ìgbà wo lo máa wò mí dà?+ Yọ mí* nínú ogun tí wọ́n gbé tì mí,+Gba ẹ̀mí mi tó ṣeyebíye* lọ́wọ́ àwọn ọmọ kìnnìún.*+
17 Jèhófà, ìgbà wo lo máa wò mí dà?+ Yọ mí* nínú ogun tí wọ́n gbé tì mí,+Gba ẹ̀mí mi tó ṣeyebíye* lọ́wọ́ àwọn ọmọ kìnnìún.*+