ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 1:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Lẹ́yìn náà, Ọlọ́run sọ pé: “Kí àwọn omi tó wà lábẹ́ ọ̀run wọ́ jọ síbì kan, kí ilẹ̀ sì fara hàn.”+ Ó sì rí bẹ́ẹ̀.

  • Jóòbù 38:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Mo sì sọ pé, ‘Ibi tí o lè dé nìyí, má kọjá ibẹ̀;

      Ìgbì rẹ tó ń ru sókè kò ní kọjá ibí yìí’?+

  • Sáàmù 136:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Ó tẹ́ ayé sórí omi,+

      Nítorí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ wà títí láé.

  • Jeremáyà 5:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 ‘Ṣé ẹ kò bẹ̀rù mi ni?’ ni Jèhófà wí,

      ‘Ṣé kò yẹ kí ẹ̀rù bà yín níwájú mi?

      Èmi ni mo fi iyanrìn pààlà òkun,

      Ó jẹ́ ìlànà tó wà títí láé tí òkun kò lè ré kọjá.

      Bí àwọn ìgbì rẹ̀ tiẹ̀ ń bì síwá-sẹ́yìn, wọn kò lè borí;

      Bí wọ́n tiẹ̀ pariwo, síbẹ̀, wọn kò lè ré e kọjá.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́