Sáàmù 6:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Pa dà, Jèhófà, kí o sì gbà mí* sílẹ̀;+Gbà mí là nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Sáàmù 51:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+
51 Ọlọ́run, ṣojú rere sí mi, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀.+ Nu àwọn àṣìṣe mi kúrò nítorí ọ̀pọ̀ àánú rẹ.+