Sáàmù 21:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọba gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà;+Nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tí Ẹni Gíga Jù Lọ ní, mìmì kan ò ní mì í* láé.+