Jeremáyà 15:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Mi ò jókòó ní àwùjọ àwọn alárìíyá, kí n sì máa yọ̀.+ Nítorí ọwọ́ rẹ wà lára mi, ṣe ni mo dá jókòó,Torí o ti fi ìbínú* kún inú mi.+
17 Mi ò jókòó ní àwùjọ àwọn alárìíyá, kí n sì máa yọ̀.+ Nítorí ọwọ́ rẹ wà lára mi, ṣe ni mo dá jókòó,Torí o ti fi ìbínú* kún inú mi.+