Jeremáyà 20:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Nítorí nígbàkigbà tí mo bá sọ̀rọ̀, ṣe ni mò ń ké jáde, tí mo sì ń kéde pé,“Ìwà ipá àti ìparun!” Nítorí pé ọ̀rọ̀ Jèhófà ti di ohun tó ń fa èébú àti yẹ̀yẹ́ fún mi láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.+
8 Nítorí nígbàkigbà tí mo bá sọ̀rọ̀, ṣe ni mò ń ké jáde, tí mo sì ń kéde pé,“Ìwà ipá àti ìparun!” Nítorí pé ọ̀rọ̀ Jèhófà ti di ohun tó ń fa èébú àti yẹ̀yẹ́ fún mi láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.+