2 Kíróníkà 36:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ṣùgbọ́n wọ́n ń fi àwọn òjíṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ ṣẹ̀sín,+ wọn ò ka ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí,+ wọ́n sì ń fi àwọn wòlíì rẹ̀ ṣe yẹ̀yẹ́,+ títí ìbínú Jèhófà fi ru sí àwọn èèyàn rẹ̀,+ tí ọ̀rọ̀ wọn sì kọjá àtúnṣe. Jeremáyà 6:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ta ló yẹ kí n bá sọ̀rọ̀, kí n sì kìlọ̀ fún? Ta ló máa gbọ́? Wò ó! Etí wọn ti di,* tí wọn kò fi lè fetí sílẹ̀.+ Wò ó! Ọ̀rọ̀ Jèhófà ti di ohun tí wọ́n fi ń ṣe ẹlẹ́yà;+Inú wọn ò sì dùn sí ọ̀rọ̀ rẹ̀.
16 Ṣùgbọ́n wọ́n ń fi àwọn òjíṣẹ́ Ọlọ́run tòótọ́ ṣẹ̀sín,+ wọn ò ka ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí,+ wọ́n sì ń fi àwọn wòlíì rẹ̀ ṣe yẹ̀yẹ́,+ títí ìbínú Jèhófà fi ru sí àwọn èèyàn rẹ̀,+ tí ọ̀rọ̀ wọn sì kọjá àtúnṣe.
10 “Ta ló yẹ kí n bá sọ̀rọ̀, kí n sì kìlọ̀ fún? Ta ló máa gbọ́? Wò ó! Etí wọn ti di,* tí wọn kò fi lè fetí sílẹ̀.+ Wò ó! Ọ̀rọ̀ Jèhófà ti di ohun tí wọ́n fi ń ṣe ẹlẹ́yà;+Inú wọn ò sì dùn sí ọ̀rọ̀ rẹ̀.