Jeremáyà 20:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 O ti yà mí lẹ́nu, Jèhófà, ẹnu sì yà mí. O lo agbára rẹ lórí mi, o sì borí.+ Mo di ẹni ẹ̀sín láti àárọ̀ ṣúlẹ̀;Gbogbo èèyàn ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́.+
7 O ti yà mí lẹ́nu, Jèhófà, ẹnu sì yà mí. O lo agbára rẹ lórí mi, o sì borí.+ Mo di ẹni ẹ̀sín láti àárọ̀ ṣúlẹ̀;Gbogbo èèyàn ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́.+