ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 22:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Gbogbo àwọn tó ń rí mi ló ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́;+

      Wọ́n ń yínmú, wọ́n sì ń mi orí wọn, pé:+

  • Jeremáyà 15:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Ìwọ ìyá mi, mo gbé nítorí pé o bí mi,+

      Ọkùnrin tí gbogbo ilẹ̀ náà ń bá jà, tí wọ́n sì ń bá fa wàhálà.

      Mi ò yáni lówó, bẹ́ẹ̀ ni mi ò yáwó lọ́wọ́ ẹnì kankan;

      Àmọ́ gbogbo wọn ń gbé mi ṣépè.

  • Jeremáyà 15:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ìwọ fúnra rẹ mọ̀, Jèhófà,

      Rántí mi kí o sì kíyè sí mi.

      Gbẹ̀san mi lára àwọn tó ń ṣe inúnibíni sí mi.+

      Má ṣe jẹ́ kí n ṣègbé* torí o kì í tètè bínú.

      O ṣáà mọ̀ pé nítorí rẹ ni mo ṣe ń fara da ẹ̀gàn yìí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́