1 Sámúẹ́lì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó ń dáàbò bo ìṣísẹ̀ àwọn adúróṣinṣin rẹ̀,+Ṣùgbọ́n a ó pa àwọn ẹni burúkú lẹ́nu mọ́ nínú òkùnkùn,+Nítorí kì í ṣe nípa agbára ni èèyàn fi ń borí.+ Òwe 10:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹni tó ń rìn nínú ìwà títọ́ yóò máa rìn nínú ààbò,+Àmọ́ àṣírí ẹni tó ń sọ ọ̀nà ara rẹ̀ di wíwọ́ yóò tú.+
9 Ó ń dáàbò bo ìṣísẹ̀ àwọn adúróṣinṣin rẹ̀,+Ṣùgbọ́n a ó pa àwọn ẹni burúkú lẹ́nu mọ́ nínú òkùnkùn,+Nítorí kì í ṣe nípa agbára ni èèyàn fi ń borí.+
9 Ẹni tó ń rìn nínú ìwà títọ́ yóò máa rìn nínú ààbò,+Àmọ́ àṣírí ẹni tó ń sọ ọ̀nà ara rẹ̀ di wíwọ́ yóò tú.+