-
2 Kíróníkà 20:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ó sọ pé: “Ẹ fetí sílẹ̀, gbogbo Júdà àti ẹ̀yin tó ń gbé Jerúsálẹ́mù àti Ọba Jèhóṣáfátì! Ohun tí Jèhófà sọ fún yín nìyí, ‘Ẹ má bẹ̀rù, ẹ má sì jáyà nítorí ọ̀pọ̀ èèyàn yìí, torí ìjà náà kì í ṣe tiyín, ti Ọlọ́run ni.+
-