Sáàmù 62:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Nítorí wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti taari rẹ̀ kúrò ní ipò gíga tó wà;*Wọ́n fẹ́ràn láti máa parọ́. Wọ́n ń fi ẹnu wọn súre, àmọ́ nínú wọn lọ́hùn-ún, wọ́n ń gégùn-ún.+ (Sélà)
4 Nítorí wọ́n gbìmọ̀ pọ̀ láti taari rẹ̀ kúrò ní ipò gíga tó wà;*Wọ́n fẹ́ràn láti máa parọ́. Wọ́n ń fi ẹnu wọn súre, àmọ́ nínú wọn lọ́hùn-ún, wọ́n ń gégùn-ún.+ (Sélà)