Sáàmù 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Nítorí kò sí èyí tó ṣeé gbára lé nínú ọ̀rọ̀ wọn;Èrò ibi ló kún inú wọn;Sàréè tó ṣí sílẹ̀ ni ọ̀fun wọn;Wọ́n ń fi ẹnu wọn pọ́nni.*+ Sáàmù 28:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Má ṣe fà mí lọ pẹ̀lú àwọn ẹni ibi, pẹ̀lú àwọn tó ń ṣe ohun búburú,+Àwọn tó ń bá ọmọnìkejì wọn sọ̀rọ̀ àlàáfíà, àmọ́ tó jẹ́ pé ibi ló wà lọ́kàn wọn.+ Sáàmù 55:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ jọ̀lọ̀ ju bọ́tà lọ,+Àmọ́ ìjà ló wà lọ́kàn rẹ̀. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tuni lára ju òróró lọ,Àmọ́ idà tí a fà yọ ni wọ́n.+
9 Nítorí kò sí èyí tó ṣeé gbára lé nínú ọ̀rọ̀ wọn;Èrò ibi ló kún inú wọn;Sàréè tó ṣí sílẹ̀ ni ọ̀fun wọn;Wọ́n ń fi ẹnu wọn pọ́nni.*+
3 Má ṣe fà mí lọ pẹ̀lú àwọn ẹni ibi, pẹ̀lú àwọn tó ń ṣe ohun búburú,+Àwọn tó ń bá ọmọnìkejì wọn sọ̀rọ̀ àlàáfíà, àmọ́ tó jẹ́ pé ibi ló wà lọ́kàn wọn.+
21 Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ jọ̀lọ̀ ju bọ́tà lọ,+Àmọ́ ìjà ló wà lọ́kàn rẹ̀. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tuni lára ju òróró lọ,Àmọ́ idà tí a fà yọ ni wọ́n.+