Jóòbù 34:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ó kọ lù wọ́n torí ìwà burúkú wọn,Níbi tí gbogbo ojú ti lè rí i,+27 Torí wọ́n ti yí pa dà, wọn ò tẹ̀ lé e mọ́,+Wọn ò sì ka àwọn ọ̀nà rẹ̀ sí;+
26 Ó kọ lù wọ́n torí ìwà burúkú wọn,Níbi tí gbogbo ojú ti lè rí i,+27 Torí wọ́n ti yí pa dà, wọn ò tẹ̀ lé e mọ́,+Wọn ò sì ka àwọn ọ̀nà rẹ̀ sí;+