Mátíù 25:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 “Ó máa wá sọ fún àwọn tó wà ní òsì rẹ̀ pé: ‘Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi,+ ẹ̀yin tí a ti gégùn-ún fún, ẹ lọ sínú iná àìnípẹ̀kun+ tí a ṣètò sílẹ̀ fún Èṣù àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀.+
41 “Ó máa wá sọ fún àwọn tó wà ní òsì rẹ̀ pé: ‘Ẹ kúrò lọ́dọ̀ mi,+ ẹ̀yin tí a ti gégùn-ún fún, ẹ lọ sínú iná àìnípẹ̀kun+ tí a ṣètò sílẹ̀ fún Èṣù àti àwọn áńgẹ́lì rẹ̀.+