9 A wá ju dírágónì ńlá+ náà sísàlẹ̀, ejò àtijọ́ náà,+ ẹni tí à ń pè ní Èṣù+ àti Sátánì,+ tó ń ṣi gbogbo ilẹ̀ ayé tí à ń gbé lọ́nà;+ a jù ú sí ayé,+ a sì ju àwọn áńgẹ́lì rẹ̀ sísàlẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀.
10 A sì ju Èṣù tó ń ṣì wọ́n lọ́nà sínú adágún iná àti imí ọjọ́, níbi tí ẹranko + náà àti wòlíì èké náà wà;+ wọ́n á sì máa joró* tọ̀sántòru títí láé àti láéláé.