Ìfihàn 12:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Mo rí àmì míì ní ọ̀run. Wò ó! Dírágónì ńlá+ aláwọ̀ iná, ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá, adé dáyádémà* méje sì wà ní àwọn orí rẹ̀; Ìfihàn 20:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó gbá dírágónì náà+ mú, ejò àtijọ́ náà,+ òun ni Èṣù+ àti Sátánì,+ ó sì dè é fún ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún.
3 Mo rí àmì míì ní ọ̀run. Wò ó! Dírágónì ńlá+ aláwọ̀ iná, ó ní orí méje àti ìwo mẹ́wàá, adé dáyádémà* méje sì wà ní àwọn orí rẹ̀;
2 Ó gbá dírágónì náà+ mú, ejò àtijọ́ náà,+ òun ni Èṣù+ àti Sátánì,+ ó sì dè é fún ẹgbẹ̀rún (1,000) ọdún.