Jẹ́nẹ́sísì 15:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+ 2 Sámúẹ́lì 22:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá. Sáàmù 3:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àmọ́, ìwọ Jèhófà ni apata tó yí mi ká,+Ògo mi+ àti Ẹni tó ń gbé orí mi sókè.+
15 Lẹ́yìn èyí, Jèhófà sọ fún Ábúrámù nínú ìran pé: “Ábúrámù, má bẹ̀rù.+ Apata ni mo jẹ́ fún ọ.+ Èrè rẹ yóò pọ̀ gan-an.”+
3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá.