1 Kíróníkà 16:28, 29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ẹ fún Jèhófà ní ohun tí ó tọ́ sí i, ẹ̀yin ìdílé gbogbo ayé,Ẹ fún Jèhófà ní ohun tí ó tọ́ sí i nítorí ògo àti agbára rẹ̀.+ 29 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá síwájú rẹ̀.+ Ẹ forí balẹ̀ fún* Jèhófà nínú aṣọ ọ̀ṣọ́ mímọ́.*+
28 Ẹ fún Jèhófà ní ohun tí ó tọ́ sí i, ẹ̀yin ìdílé gbogbo ayé,Ẹ fún Jèhófà ní ohun tí ó tọ́ sí i nítorí ògo àti agbára rẹ̀.+ 29 Ẹ fún Jèhófà ní ògo tí ó yẹ orúkọ rẹ̀;+Ẹ mú ẹ̀bùn dání wá síwájú rẹ̀.+ Ẹ forí balẹ̀ fún* Jèhófà nínú aṣọ ọ̀ṣọ́ mímọ́.*+