-
Sáàmù 25:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Má ṣe jẹ́ kí àwọn ọ̀tá mi yọ̀ mí.+
-
-
Sáàmù 41:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ohun tí màá fi mọ̀ pé inú rẹ dùn sí mi nìyí:
Kí àwọn ọ̀tá mi má lè kígbe ìṣẹ́gun lé mi lórí.+
-