Àìsáyà 54:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Mo fi ojú mi pa mọ́ fún ọ fún àkókò díẹ̀ torí inú bí mi gidigidi,+Àmọ́ màá ṣàánú rẹ nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó wà títí láé,”+ ni Jèhófà, Olùtúnrà rẹ+ wí.
8 Mo fi ojú mi pa mọ́ fún ọ fún àkókò díẹ̀ torí inú bí mi gidigidi,+Àmọ́ màá ṣàánú rẹ nítorí ìfẹ́ tí kì í yẹ̀, tó wà títí láé,”+ ni Jèhófà, Olùtúnrà rẹ+ wí.