Àìsáyà 47:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+ Ìsíkíẹ́lì 39:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Àwọn orílẹ̀-èdè á sì wá mọ̀ pé torí ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì, torí wọ́n hùwà àìṣòótọ́ sí mi ni wọ́n fi lọ sí ìgbèkùn.+ Torí náà, mo fi ojú mi pa mọ́ fún wọn,+ mo fi wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́,+ idà sì pa gbogbo wọn.
6 Inú bí mi sí àwọn èèyàn mi.+ Mo sọ ogún mi di aláìmọ́,+Mo sì fi wọ́n lé ọ lọ́wọ́.+ Àmọ́ o ò ṣàánú wọn rárá.+ Kódà, o gbé àjàgà tó wúwo lé àgbàlagbà.+
23 Àwọn orílẹ̀-èdè á sì wá mọ̀ pé torí ẹ̀ṣẹ̀ ilé Ísírẹ́lì, torí wọ́n hùwà àìṣòótọ́ sí mi ni wọ́n fi lọ sí ìgbèkùn.+ Torí náà, mo fi ojú mi pa mọ́ fún wọn,+ mo fi wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́,+ idà sì pa gbogbo wọn.