2 Sámúẹ́lì 5:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Dáfídì wá mọ̀ pé Jèhófà ti fìdí ìjọba òun múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì+ àti pé ó ti gbé ìjọba òun ga+ nítorí àwọn èèyàn Rẹ̀ Ísírẹ́lì.+ Sáàmù 89:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí ìwọ ni ògo agbára wọn,+A sì gbé agbára* wa ga torí pé o tẹ́wọ́ gbà wá.+
12 Dáfídì wá mọ̀ pé Jèhófà ti fìdí ìjọba òun múlẹ̀ lórí Ísírẹ́lì+ àti pé ó ti gbé ìjọba òun ga+ nítorí àwọn èèyàn Rẹ̀ Ísírẹ́lì.+