1 Sámúẹ́lì 2:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+
10 Jèhófà yóò fọ́ àwọn tó ń bá a jà sí wẹ́wẹ́;*+Yóò sán ààrá lù wọ́n láti ọ̀run.+ Jèhófà yóò ṣe ìdájọ́ títí dé gbogbo ìkángun ayé,+Yóò fún ọba rẹ̀ ní agbára+Yóò sì gbé ìwo* ẹni àmì òróró rẹ̀ ga.”+