ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 40:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Àmọ́ aláìní ni mí, mi ò sì ní olùrànlọ́wọ́;

      Kí Jèhófà fiyè sí mi.

      Ìwọ ni olùrànlọ́wọ́ mi àti olùgbàlà mi;+

      Ọlọ́run mi, má ṣe jẹ́ kó pẹ́.+

  • Sáàmù 70:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 70 Ọlọ́run, gbà mí;

      Jèhófà, tètè wá ràn mí lọ́wọ́.+

  • Sáàmù 71:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Gbà mí sílẹ̀, kí o sì gbà mí là nínú òdodo rẹ.

      Tẹ́tí sí mi,* kí o sì gbà mí sílẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́