Sáàmù 54:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wò ó! Ọlọ́run ni olùrànlọ́wọ́ mi;+Jèhófà wà pẹ̀lú àwọn tó ń tì mí* lẹ́yìn. Àìsáyà 50:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àmọ́ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́.+ Ìdí nìyẹn tí ìtìjú ò fi ní bá mi. Ìdí nìyẹn tí mo fi ṣe ojú mi bí akọ òkúta,+Mo sì mọ̀ pé ojú ò ní tì mí. Hébérù 13:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+
7 Àmọ́ Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́.+ Ìdí nìyẹn tí ìtìjú ò fi ní bá mi. Ìdí nìyẹn tí mo fi ṣe ojú mi bí akọ òkúta,+Mo sì mọ̀ pé ojú ò ní tì mí.
6 Ká lè nígboyà gidigidi, ká sì sọ pé: “Jèhófà* ni olùrànlọ́wọ́ mi; mi ò ní bẹ̀rù. Kí ni èèyàn lè fi mí ṣe?”+