Sáàmù 57:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Àwọn kìnnìún yí mi* ká;+Àárín àwọn tó fẹ́ fà mí ya ni mo dùbúlẹ̀ sí,Àwọn tí eyín wọn jẹ́ ọ̀kọ̀ àti ọfà,Tí ahọ́n wọn sì jẹ́ idà mímú.+
4 Àwọn kìnnìún yí mi* ká;+Àárín àwọn tó fẹ́ fà mí ya ni mo dùbúlẹ̀ sí,Àwọn tí eyín wọn jẹ́ ọ̀kọ̀ àti ọfà,Tí ahọ́n wọn sì jẹ́ idà mímú.+