-
Sáàmù 12:3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
3 Jèhófà máa gé gbogbo ètè tó ń pọ́nni kúrò
Àti ahọ́n tó ń sọ̀rọ̀ ìgbéraga,+
-
Sáàmù 63:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Àmọ́ ọba yóò máa yọ̀ nínú Ọlọ́run.
Gbogbo ẹni tó ń fi Í búra yóò máa yìn Ín,*
Nítorí a ó pa àwọn tó ń parọ́ lẹ́nu mọ́.
-
-
-