Àìsáyà 35:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ sọ fún àwọn tó ń ṣàníyàn nínú ọkàn wọn pé: “Ẹ jẹ́ alágbára. Ẹ má bẹ̀rù. Ẹ wò ó! Ọlọ́run yín máa wá gbẹ̀san,Ọlọ́run máa wá láti fìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹni.+ Ó máa wá gbà yín sílẹ̀.”+
4 Ẹ sọ fún àwọn tó ń ṣàníyàn nínú ọkàn wọn pé: “Ẹ jẹ́ alágbára. Ẹ má bẹ̀rù. Ẹ wò ó! Ọlọ́run yín máa wá gbẹ̀san,Ọlọ́run máa wá láti fìyà ẹ̀ṣẹ̀ jẹni.+ Ó máa wá gbà yín sílẹ̀.”+