Jeremáyà 51:56 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 56 Nítorí apanirun máa dé sórí Bábílónì;+A ó mú àwọn jagunjagun rẹ̀,+A ó ṣẹ́ ọfà* wọn sí wẹ́wẹ́,Nítorí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run ẹ̀san.+ Ó dájú pé ó máa gbẹ̀san.+
56 Nítorí apanirun máa dé sórí Bábílónì;+A ó mú àwọn jagunjagun rẹ̀,+A ó ṣẹ́ ọfà* wọn sí wẹ́wẹ́,Nítorí Jèhófà jẹ́ Ọlọ́run ẹ̀san.+ Ó dájú pé ó máa gbẹ̀san.+