Jeremáyà 50:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Idà kan wà tó dojú kọ àwọn tó ń sọ ọ̀rọ̀ asán,* wọ́n á sì hùwà òmùgọ̀. Idà kan wà tó dojú kọ àwọn jagunjagun rẹ̀, jìnnìjìnnì á sì bò wọ́n.+
36 Idà kan wà tó dojú kọ àwọn tó ń sọ ọ̀rọ̀ asán,* wọ́n á sì hùwà òmùgọ̀. Idà kan wà tó dojú kọ àwọn jagunjagun rẹ̀, jìnnìjìnnì á sì bò wọ́n.+