Jeremáyà 51:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Àwọn jagunjagun Bábílónì ti ṣíwọ́ ìjà. Wọ́n jókòó sínú àwọn odi agbára wọn. Okun wọn ti tán.+ Wọ́n ti di obìnrin.+ Wọ́n ti sọ iná sí àwọn ilé rẹ̀. Wọ́n ti ṣẹ́ àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.+
30 Àwọn jagunjagun Bábílónì ti ṣíwọ́ ìjà. Wọ́n jókòó sínú àwọn odi agbára wọn. Okun wọn ti tán.+ Wọ́n ti di obìnrin.+ Wọ́n ti sọ iná sí àwọn ilé rẹ̀. Wọ́n ti ṣẹ́ àwọn ọ̀pá ìdábùú rẹ̀.+