Jeremáyà 50:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ẹṣin wọn àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn,Tó sì dojú kọ onírúurú àjèjì tó wà láàárín rẹ̀,Wọ́n á dà bí obìnrin.+ Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ìṣúra rẹ̀, ṣe ni wọ́n á kó wọn lọ.+
37 Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ẹṣin wọn àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun wọn,Tó sì dojú kọ onírúurú àjèjì tó wà láàárín rẹ̀,Wọ́n á dà bí obìnrin.+ Idà kan wà tó dojú kọ àwọn ìṣúra rẹ̀, ṣe ni wọ́n á kó wọn lọ.+