Àìsáyà 13:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jìnnìjìnnì bo àwọn èèyàn náà.+ Iṣan wọn sún kì, wọ́n sì ń jẹ̀rora,Bí obìnrin tó ń rọbí. Wọ́n ń wo ara wọn tìbẹ̀rù-tìbẹ̀rù,Ìrora sì hàn lójú wọn.
8 Jìnnìjìnnì bo àwọn èèyàn náà.+ Iṣan wọn sún kì, wọ́n sì ń jẹ̀rora,Bí obìnrin tó ń rọbí. Wọ́n ń wo ara wọn tìbẹ̀rù-tìbẹ̀rù,Ìrora sì hàn lójú wọn.