Róòmù 4:7, 8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 “Aláyọ̀ ni àwọn tí a dárí ìwà wọn tí kò bófin mu jì, tí a sì bo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀;* 8 aláyọ̀ ni ẹni tí Jèhófà* kò ka ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ sí lọ́rùn lọ́nàkọnà.”+
7 “Aláyọ̀ ni àwọn tí a dárí ìwà wọn tí kò bófin mu jì, tí a sì bo ẹ̀ṣẹ̀ wọn mọ́lẹ̀;* 8 aláyọ̀ ni ẹni tí Jèhófà* kò ka ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ sí lọ́rùn lọ́nàkọnà.”+