Sáàmù 32:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Aláyọ̀ ni ẹni tí a dárí àṣìṣe rẹ̀ jì, tí a sì bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀.*+ 2 Aláyọ̀ ni ẹni tí Jèhófà kò ka ẹ̀bi sí lọ́rùn,+Ẹni tí kò sí ẹ̀tàn nínú ẹ̀mí rẹ̀.
32 Aláyọ̀ ni ẹni tí a dárí àṣìṣe rẹ̀ jì, tí a sì bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀.*+ 2 Aláyọ̀ ni ẹni tí Jèhófà kò ka ẹ̀bi sí lọ́rùn,+Ẹni tí kò sí ẹ̀tàn nínú ẹ̀mí rẹ̀.